Welcome:
OLORUN!
OLODUMARE! ELEDA
Kabiesi! Olorun Olodumare, Eleda orun on aye. Oba
akoko ati Oba igbehin. Alayeluwa Oba olowo gbogboro ti ngbomo Re ninu ofin.
Olorun Adimula, Oba ti npa ojo iku da. Adake dajo, Ajalaye Ajalorun. Mo dupe ire
ana, modupe ire oni, mowa tun dupe ire ola. Jowo fun mi ni alafia pelu ogbon,
imo ati oye. Iwaju ti ofimi si, jowo mase somi di ero ehin o. Ki eni osan mi, ki
ola osan mi, ki ojo gbogbo osan mi pelu ile at ona mi o. Ashe!
OBATALA:
To my Orisanla! Baba mi Obatala, Eruwaa daaji! Eruwaa daaji! Eruwaa daaji!
Orisha nla Aran Ajigun agba, omojo alasire, eni nsoju, eni nse mun, Oluorogbo,
Orisha Kire, Orisha Jugbe, ki ebawa taye yi se o, ashe!. Oba ALASHE! Obatala is the Alase Orisha as it was revealed in Odu Eleji-Ogbe that: All the rivers of the world put together, are not as remarkable as the Ocean. All the streams of the world put together, are less than the Lagoon. Cast Ifa for Obatala Oseremagbo, on the day he was to be made king, when all the deities wanted to take away one of its powers. Orunmila refused to grant their wish, so did
Elegbara. There is no Odu Ifa that takes precedence over Ejiogbe. Ejiogbe is the paramount Odu.
Holly Obatala: You are the True Head of gbogbo Orisha. Obatala Your are the
Alashe and Alade Orisha. Ejiogbe, you are the paramount Odu. Any river that does not recognize the pre-eminence of the Ocean, will dry up completely. Before savannah burns, it will first dry up.
I request for wealth from Olosa, the second in command. I received this but not sufficiently. I request for wealth from Olokun Seniade, the king of all rivers. I received but not sufficiently. Who does not know that
it is only the wealth Giving by God Almighty (Olorun, Olodumare ati Eleda) that last for life? Ase.
Ejiogbe
Kabiesi: Oba Sijuade
Olubuse II.
OOni of Ife! Oba Sijuade
Olubuse II. Wori wori o. Eruwa daaji o, Mo woko. Mo waya, mo wa Yemoo Oboniba.
Owo para, ese para, asegbo, aseto, kama yun kama wa, kese wa mase na o. Ki iru
kere jeje ki odo kini, Ki Ile Ife oroju, ki Ile Ife oraye. Ki Ilogbo Ekiti oroju,
ki Ilogbo Ekiti oraye o. Ki amun omun nyin pepe pe o. Ki igba yin tu gbogbo omo
Yoruba lara o, ki igba yin tu gbogbo Nigeria lara o, Ashe!
Araba Ife
Ki emin ola gun pepe o, ki ade pe lori ki bata pe lese, igba yin tu gbogbo omo
Yoruba lara o, ki igba yin tu gbogbo Nigeria lara o, ki igba yin tu wa
lara jake jado gbogbo agbaye o. Waa gbo! waa to, Baba wa o Ashe!
Oloye Bode Fasuyi
Obanurin Ikire Of Ife (Obatala)
Otun Elejelu Awo Agbaye (Ifa-Oke Itashe, Ile-Ife)
Let us attune ourselves with the Divine Power of Olodumare, Ifa and Oriza and
make sure we consult Ifa before problem starts! Aboru, Aboye, Abosise!
Contact us | View site map

|

|